BY OGUNYEMI OLUSEGUN T
PRAY WITH ISAIAH 45
1. Let God be God in my life in this year 2023, in the name of Jesus.
2. Lord let your promises concerning my life this year come to fulfillment in the name of Jesus.
3 I receive strength and grace to do your will always this year.
4. Lord help me to use all that I have to serve you this year.
5. 2023 shall be my year of Testimonies, Amen.
YORUBA EDITION
1. Je ki Oluwa ki o je Oluwa ninu aye mi ninu odun 2023 yi loruko Jesu.
2. Oluwa je ki gbogbo ileri ti E ni funmi ninu odun yi wasi imuse ni oruko Jesu.
3. Mo gba okun ati ore ofe lati le ma se ife Re nigba gbogbo ninu odun yi.
4. Oluwa ranmilowo lati fi ohun gbogbo ti mo ni sin o ninu odun yi.
5. 2023 yio je odun Eri mi. Amin.
Jesus is Lord no controversy.
SPONSORED ADS 👇👇 👇
SPONSORED ADS 👇👇👇
A1 PREMIER MODEL ACADEMY LTD, OSOGBO, OSUN STATE, NIGERIA
SPONSORED ADS 👇👇👇
No comments