COMMAND YOUR DAY PRAYER POINTS FOR TODAY MONDAY13TH SEPTEMBER 2021
BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN T
1. Lord, I thank You for the salvation of the multitude.
2. Thou Spirit of the Lord move like a wind, locate and direct my ordained helpers to me, in Jesus’ name.
3. Every secret I need to know about my environment be revealed in Jesus’ name.
5. I reclaim all the ground I have lost to the enemy, in Jesus’ name.
5. Lord, by a strong east wind, drive away all the darkness surrounding my
help environment in Jesus’ name.
YORUBA EDITION
1. Oluwa, modupe lowo Re fun igbala opo eniyan.
2. Iwo Emi Oluwa fe bi iji, sawari ki o si dari awon oluranlowo mi ti a ti yan si mi ni oruko Jesu.
3. Gbogbo asiri ti mo nilo lati mo nipa ayika mi, tu fun mi ni oruko Jesu.
4.Mo gba gbogbo ile ti mo ti sonu pada ni oruko Jesu.
5.Oluwa, nipa afefe lile ti ila orun, le gbogbo awon okunkun ti o yi ayinka iranlowo mi ka ni oruko jesu Kristi.
Jesus is Lord no controversy.