BY OGUNYEMI OLUSEGUN T.
PRAY WITH PSALM 114
1. Lord I thank you for who you are in my life and all that you have given to me.
2. I destroy all agenda of the enemies to waste and delay my moment of blessings in Jesus’ name.
3. Everything in me that is sponsored to waste my life, time and opportunities be destroyed in Jesus’ name.
4. Mercy of God to recover and accelerate, fall upon me now in Jesus’ name.
5. Today, I begin to walk in the light of God. Amen.
YORUBA EDITION
1. Oluwa mi, mo dupe lowo re fun eni ti e je ninu aye mi ati oun gbogbo ti e ti fun mi.
2. Mo ba gbogbo ipunu ota lati je kin fa seyin ati lati je ki akokomi sofo je l’oruko Jesu.
3. Oun gbogbo ti o wa ninu mi to n di Emi Mimo lowo, gbina l’oruko Jesu.
4. Oluwa, tu gbogbo akoko anfani mi se l’oruko Jesu.
5. Loni, mo bere sini rin ninu imole ni oruko Jesu. Amim.
Jesus is Lord no controversy.
SPONSORED ADS 👇 👇
SPONSORED ADS 👇👇
No comments