BUY OGUNYEMI OLUSEGUN T
1. Error of my parents that has hidden me, Blood of Jesus set me free.
2. Debt of my generation which I am compelled to pay, God of mercy take over from me.
3. Shout arrows from my foundation five times , jump out by fire in the name of Jesus.
4. O my head, receive new oil in the name of Jesus.
5. You arrow of fear, you are a stranger in my body, jump
out by fire. Amen
YORUBA EDITION
1. Asise awon obi mi to gbe mi pa mo, Eje Jesu tu mi sile.
2. Gbese ti iran mi je ti won ni emi ni maa san, Olorun
Aanu gba l'owo mi.
3. Pariwo “ofa lati iran mi” lemarun, fo jade pelu ina ni
oruko Jesu.
4. Ori mi, gba ororo titun ni oruko Jesu.
5. Iwo ofa iberu, ajeji loje ninu ara mi, fo jade pelu ina. Amin.
Jesus is Lord no controversy.
No comments