BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN T
1. Anyone in custody of my help within 24hours come and drop it for me in Jesus’ name.
2. Voice of critics be silent around me in Jesus’ name.
3.I receive grace to offer profitable service for my maximum lifting in Jesus’ name.
4. Pray in the Holy Ghost for 15 minutes.
YORUBA EDITION
1. Gbogbo eni ti o waa ni isakoso iranlowo mi, laarin wakati merinlelogun, e ma jowo re fun mi, ni oruko Jesu.
2. Ohun alatako, e
panu mo ni ayika mi l’oruko Jesu.
3. Mo gba ore-ofe lati se ise ti o lere fun igbe dide mi ni oruko Jesu.
4. Gbadura ninu Emi fun isejun marundinlogun.
Jesus is Lord no controversy.
No comments