BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
Email: [email protected]
PRAY WITH PSALM 68
1 .Worship God this morning locate 3 songs
2. O ye redeemed of the Lord, locate 3 songs and dance to the Lord.
3. Everything I am doing that angers God, expose it by
mercy and forgive me in the name of Jesus.
4. O God of Mercy set Your revival fire into the lives of all Your servants both in this country and the world at
large.
5. O Lord, arise and use Your power to put to shame every enemy of my progress in the name of Jesus.
YORUBA EDITION
1 .Yin Olorun ni aro yi pelu orin iyin meta.
2. Iwo ti ati rapada, wa orin iyin meta ko si Oluwa ki o si ma jo niwaju Re.
3. Gbogbo oun ti mose to nbi Olorun ninu fi aanu han ki o si darijimi l'oruko Jesu.
4. Olorun aanu, da ina isoji Re si inu aiye gbogbo awon
iranse Re ni orile-ede yi ati ni agbaiye.
5. Olorun dide ki O si lo gbogbo oun to nbe ni ikawo Re lati doju ti gbogbo ota igbesoke mi l'oruko Jesu. Amim.
JESUS IS LORD NO CONTROVERY (08036816264)
No comments