BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
Pray with Psalm 8
1. Every arrow of spiritual failure, your mission is over in my life, jump out by fire, in Jesus name.
2. Oh Lord, give me passion to fulfill Your purpose for my life in Jesus' name.
3. Lord, make me Your battle axe and weapoun of war in Jesus' name.
4. Holy Ghost fire, possess me afresh.
5. Lord, make me a person after Your heart like David in
Jesus' name.
JESUS IS LORD
YORUBA EDITION
1. Gbogbo ofa ijakule ninu emi, ise yin pari ninu aiye mi, e fo jade pelu ina.
2. Oluwa, fun mi ni itara lati pari ise to ran mi l’aiye ni
oruko Jesu.
3. Oluwa, se mi ni oun ija ati irinse ogun ni oruko Jesu.
4. Ina Emi-Mimo, gbe mi wo l’otun.
5. Oluwa, se mi ni eni bi okan Re bi Dafidi ni oruko Jesu.
JESU IN OLUWA
By Pastor Ogunyemi T. O.
Email: [email protected]
No comments