PRAY WITH PSALM 2
1. I thank You Lord for You are the only one that
answers prayer.
2. Every messenger of death assigned to defraud me of
my inheritance, begin to kill yourself in Jesus' name
3. Zeal of the Lord, consume me to be able to identify
with Jesus openly.
4. Lord by mercy, release my inheritance to me in Jesus'
name.
5. Flood my heart with the light of heaven.
6. Lord by mercy, turn my curses to blessing.
7. Rage of blood drinkers of the night, drink your own
blood in Jesus' name.
8. Every power organized to embarrass me, be scattered by fire in Jesus' name.
Yoruba Translation:
KOKO ADURA FUN 28/10/20 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 2.
1. MODUPE l'owo Re Oluwa to ri wipe Iwo nikan ni
oun gbo adura.
2. Gbogbo iranse iku eleyi ti a yan wipe ki o ja mi lole ini
mi, e bere si ni para yin ni oruko Jesu
3. Itara Olorun, gbe mi wok i nbale mo Jesu nikan
nigbangba.
4. Olorun, nipa aanu, yonda ini mi fun mi ni oruko Jesu.
5. Kun okan mi pelu imole t'orun.
6. Olorun, nipase aanu, yi egun mi pada si ibukun.
7. Ijakadi awon mujemuje oru, e mu eje ara yin l'oruko
Jesu.
8. Gbogbo agbara ti a ran nise lati doju ti mi, e tuka pelu ina ni oruko Jesu.
PASTOR TIMOTHY OLUAEGUN OGUNYEMI
No comments