BY OLUSEGUN TIMOTHY O.
READ: PSALM 104
1 Lord, I thank You for You hear me whenever I pray in Jesus' name.
2 .I will not love what will kill me in Jesus' name.
5 .Anything in my foundation that wants to destroy my destiny, be uprooted in Jesus' name.
4 Anointing to pray ceaselessly, envelope me.
5 Spiritual wounds and injuries I have sustained, be healed by the Blood of Jesus. Amen.
YORUBA EDITION
1. Oluwa, modupe lowo Re nitoripe O ngbo adura mi nigbati mo ba gbaa ni oruko Jesu.
2 .Emi o ni fe ohun ti yio pa mi ni oruko Jesu.
3 .Ohunkohun ninu ipinle mi to fe ba ayanmo mi je, ma fatu ni oruko Jesu.
4.Ifamiororo yan lati ma gba adura lai sinmi ati lai se aare subomi.
5 .Gbogbo ogbe emi ti mo ti gba, e san nipa Eje Jesu. Amin.
Jesus is Lord no controversy.
No comments