BY OGUNYEMI OLUSEGUN T.
1. I receive grace to trust God even in all of my battles in Jesus’ name.
2. Jesus Christ fulfilled destiny and I will fulfill it as well in Jesus’ name.
3. Father, help me to finish well and strong, in Jesus’ name.
4. I will not run ahead of my set time in Jesus’ name.
5. Lord, help me to fully understand knowledge of the scripture. Amen.
YORUBA EDITION
1. Mo gba ore-ofe lati gbekele Olorun ninu gbogbo ilakoja mi l’oruko Jesu.
2. Jesu Kristi se aseyoori ayonmo, beni emi naa yoo se aseyoori l’oruko Jesu.
3. Baba ranmilowo lati pari daradara pelu agbara ni oruko Jesu.
4. Emi ki yoo sare koja akoko ti a yan fun mi ni oruko Jesu.
5. Oluwa, ranmi lowo lati ni oye kikun imo ti oro Olorun. Amin.
Jesus is Lord no controversy.
SPONSORED ADS 👇👇
SPONSORED ADS 👇👇
No comments