BY OGUNYEMI OLUSEGUN T.1
PRAY WITH PSALM 100
1. Thank You Father for touching my eyes to see the new height You are taking me to.
2. Every power contending with me over my possession be destroyed in Jesus’ name.
3. Every padlock of the power of darkness that has tied me down to the same spot, break by fire in Jesus’ name.
4. I command the earth and all the elements to cooperate with me in Jesus’ name.
5. Power to prevail in battle of destiny possess me in Jesus’ name.
YORUBA EDITION
1. Baba, Ese ti E fi owo kan oju mi lati ri ipele tuntun ti E tun nmumi lo.
2. Gbogbo agbara ton ba mi ja lori ini mi, e parun ni oruko Jesu.
3. Gbogbo agadagodo agbara okunkun ti o ti so mi mole si oju kan, fo pelu ina
ni oruko Jesu.
4. Mo pase fun aye ati oun gbogbo ti o wa ninu re, ki o fi owo so owo po pelu
mi ni oruko Jesu.
5. Agbara lati bori ninu ogun ayanmo gbe mi wo ni oruko Jesu.
Jesus is Lord no controversy.
SPONSORED ADS 👇👇
No comments