BY OGUNYEMI OLUSEGUN T
PRAY WITH ISAIAH 31
1. Sing at least three songs of praise to the Lord.
2. Every project which I have abandoned before now, be resumed by mercy in Jesus’ name
3. Lord, teach my hands to war and my finger to fight that I may possess my
possessions in Jesus’ name.
4. Every strange magnet magnetizing me to wrong help and helpers, be
neutralized by the Blood of Jesus.
5. Let every satanic gate that has locked me out of my inheritance open now in
Jesus’ name.
YORUBA EDITION
1. Ko bi orin iyin meta si Olorun.
2. Gbogbo adawole ti mo ti pa ti saaju akoko yi, bere Ise pelu aanu, ni oruko Jesu.
3. Oluwa, ko owo mi ni ogun jija, ati ika ki ni ija, kin ba le gba ini mi pada.
4. Gbogbo onfa ajoji eleyi ti on fa mi lo si ibi iranlowo odi ati oluranlowo odi, e
di asan pelu eje Jesu.
5. Je ki gbogbo enu bode okunkun ti o ti ti mi jade kuro ninu ipin mi si lesekese
ni oruko Jesu, Amin.
Jesus is Lord no controversy.
Sponsored ads 👇 👇
No comments