BY OGUNYEMI OLUSEGUN T
PRAY WITH PSALM 3
1. Appreciate God for His love.
2. O Lord, forgive me from every unfaithfulness.
3. Lord, give me my personal Pentecost in Jesus' name.
4. I bind and paralyze every spirit of error programmed against me in Jesus' name.
5. I withdraw the name of my children from the book of death in Jesus' name.
YORUBA EDITION
1. Gbe Olorun ga fun ife Re.
2. Oluwa, dari gbogbo aisododo mi ji mi.
3. Oluwa, fun mi ni Pentikosti temi ni oruko Jesu.
4. Mo gbede mo si yalaro gbogbo emi asise ti a se lodi si mi ni oruko Jesu.
5. Mo fa oruko awon omo mi yo kuro ninu iwe iku ni oruko Jesu.
Jesus is Lord no controversy.
No comments