news

Followers

COMMAND YOUR DAY PRAYER POINTS FOR TODAY THURSDAY 23RD SEPTEMBER, 2021

BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN T








READ PSALM 107



1. Sing a song to the King of kings. 


2. Father, grant me grace to live by your principle in the world and follow Your 

guidelines in all I do, in Jesus’ name.


3. Lord, help my children never to partake in anything that will attract curses to 

their lives, in Jesus’ name.


4. Giving is and act and a spirit. My Father, my Father, give me the Spirit of 

giving in Jesus’ name.


5. Lord, grant me grace to identify things that are working against my ability to spend time alone with You and grace to deal with them in Jesus’ name.


6. Occult court set to de-robe me of divine assistance scatter by fire in Jesus’ name. Amen.


          YORUBA EDITION


1. Ko orin kan siy Oba awon oba.


2. Bab, fun mi ni ore-ofe lati le ma rin ninu ila Re ninu aiye ki nsi ma rin nipa 

itona Re ninu oun gbogbo ti mob a nse ni oruko Jesu.


3. Oluwa, ran awon omo mi lowo lati ma kopa ninu oun ti yio fa egun sinu aiye 

won ni oruko Jesu.


4. Ififunni je ise ati emi. Baba mi, Baba mi, fun mi ni emi ififunni ni oruko Jesu.


5. Oluwa, fun mi ni ore-ofe lati le moa won oun ti nsise lodi si ati ma wa pelu 

Re ati ore-ofe lati bori won ni oruko Jesu.


6. Ile-ejo okunkun ti o mura lati ma fi aiye gba iranwo atoke fun mi, tuka pelu 

in ani oruko Jesu. Amim.


   Jesus is Lord no controversy.

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts