news

Followers

COMMAND YOUR DAY PRAYER POINTS FOR THURSDAY 26TH AUGUST 2021

BY OGUNYEMI OLUSEGUN T



1. Worship the God of mercy with a song.


2. I receive grace to be totally sold into the will of God.


3. I pray daily for the grace to work in purity beccfore the Lord.


4. Lord, cleanse me from all unrighteousness.


5. Ability to discern the strategies of the enemies, possess me in Jesus’ name.


6. Every seed of hell in my life, be uprooted by mercy in Jesus’ name. Amen.


          YORUBA EDITION


1. Yin Olorun aanu pelu orin kan.


2. Mo gba ore-ofe lati wa ninu ife Oluwa patapata.


3. Mo n gbadura lojojumo, fun ore-ofe lati ma sise ninu iwa mimo niwaju Oluwa.


4. Oluwa, we mi mo kuro ninu gbogbo aisododo.


5. Ore-ofe lati mo gbogbo eto awon ota, gbe mi wo ni oruko Jesu.


6. Gbogbo irugbin orun apaadi ninu aye mi, fa tu ti gbongbo ti gbongbo in oruko Jesu. Amim


    Jesus is Lord no controversy.

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts