BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
Email: [email protected]
PRAY WITH PSALM 3
Sing a new song to God.
1. O Lord, let Your righteousness reign in all the branches of government in this country.
2. Oil of wisdom and organization with the fear of God fall in all the leaders of this country in the name of
Jesus.
3. Every council of darkness that are plotting over my case, be scattered by fire in the name of Jesus.
4. Every household power waiting forget me to end empty handed this year, and catch fire and burn to ashes.
5. Every monitoring spirit over my case, catch fire in the name of Jesu. Amen.
YORUBA EDITION
Ko orin tuntu si Oluwa
1. Oluwa, jeki ododo Re joba ni gbogbo eka isejoba ni
orile ede yi.
2. Ororo ogbon ati isakoso pelu iberu Oluwa, ma bo l'ori awon adari wa l'oruko Jesu.
3. Gbogbo igbimo awon okunkun to njiroro l'ori oro mi, ara Oluwa tu won ka.
4. Agbara ile lapoti njoko dedi to ni nu ko ni ri nkan gbamu ni odun yi, gbina daanu l'oruko Jesu.
5. Gbogbo oju atopinpin l'ori oro mi, gbina daanu l'oruko Jesu.
Jesus is Lord no controversy.
No comments