BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
1. Locate 2 worship songs to the Lord.
2. Lord, before I finish these prayers let Your angels start working on my case in the name of Jesus.
3. Voice of progress manifest in my life in the name of Jesus.
4. In every where that I have been rejected, I receive the voice of acceptance from today in the name of Jesus.
5. Under the voice of condemnation, I become justified from today. Amen
YORUBA EDITION
1. Wa orin iyin mjei ki o fi yin Oluwa.
2. Ki nto gba adura yi tan, Oluwa je ki awon angeli Re bere si ni sise nitori temi l'oruko Jesu.
3. Ohun asunnisiwaju, farahan ninu ayanmo mi.
4. Gbogbo ibi ti a ti ko mi sile, mo gba ohun itewogba lati oni lo l'oruko Jesu.
5. Ni abe ohun idalebi, mo di eni idalare lati oni lo. Amim.
JESUS IS LORD NO CONTROVERY.
(08036816264)
SHALOM
No comments