BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
Email: [email protected]
PRAY WITH PSALM 18
1. Worship God this morning.
2. I shall not end in shame over my children.
3. O Lord, envelope me with fire.
4. O God, hide me from danger and untimely death.
5. Messenger of death, return to your sender in Jesus' name.
6. Arrow of wickedness in the place of prayer, backfire in the name of Jesus.
YORUBA EDITION
1, Yin Olorun ni owuro yi.
2. Emi o ni gba ere itiju lori awon omo mi.
3. Oluwa, fi ina yi mi ka.
4. Olorun, gbe mi pamo kuro ninu ewu ati iku ojiji.
5. Onise iku, pada si ibi ti a ti ran o ni oruko Jesu.
6. Ofa awon ika ni ibi adura, pada ni oruko Jesu.
JESUS IS LORD
No comments