news

Followers

COMMAND YOUR DAY: PRAYER POINTS FOR TODAY WEDNESDAY 7TH APRIL 2021

PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY

EMAIL: [email protected]PRAY WITH PSALM 2


1. Lord, I thank You for Your merciful acts and Your forgiving grace (sing a song).

2. Lord, forgive me for all my wrong doings and disobedience to Your will.

3. Every power sitting in the lurking places of the village to attack my destiny, be scattered.


4. Every rage of the heathen, be dismantled by God's voice.

5. Every grip of heathen over my inheritance, be broken by thunder.

6. The heathen will not say, 'where is my God'

7. By mercy, I shall not bear the shame of the heathen anymore.

8. Every dominion and rulership of the heathen over my life, be dethroned in Jesus' name.

9. I withdraw every of my inheritance from the camp of the heathen.

10. Every strongholds of the heathen around me, be broken by thunder


YORUBA EDITION:


GBADURA PELU ORIN DAFIDI 2


1. OLUWA, modupe fun ise aanu Re ati ore-ofe idariji (ko orin kan si Olorun).

2. Oluwa, dari gbogbo ese mi ji mi ati awon aigboran si ife Re.

3. Gbogbo agbara ti o joko si ibi ikoko ni ilu mi lati gbogun ti ayanmo mi, e tuka.

4. Gbogbo ibinu fufu ota, tuka nipase ohun Olorun.

5. Gbogbo owo ota l'ori ini mi, fo danu pelu ara ni oruko Jesu


6. Awon ajeji tabi alaigbagbo ki yio bere wipe nibo ni Olorun mi wa.

7. Nipa aanu, emi ki yio ru itiju awon alaigbagbo mo.

8. Gbogbo ijegaba ati idari awon keferi l'ori aiye mi, Eje

Jesu ro won l'oye.

9. Mo gba gbogbo awon ini mi kuro ni ago awon keferi.

10. Gbogbo ibi giga awon keferi ni ayika mi, fo pelu ara.


PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY

EMAIL: [email protected]

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts