By Pastor Ogunyemi Olusegun Timothy
PRAY WITH PSALM 5
1. Select three songs of praises to the Lord.
2. Every arrow of back to square one shot against me, back fire in Jesus' name.
3. I declare every financial miracle I have lost, be restored back in Jesus' name.
4. Every evil network backing repeated problems in my life, scatter by fire.
5. I reject every spirit of dry land. I claim divine favor and divine prosperity.
YORUBA EDITION
1. Wa orin meta ki o fi yin Oluwa.
2. Gbogbo ofa idapada si ibeere ti a ta lu mi, pada si ibi ti won ti ta o ni oruko Jesu.
3. Mo pase pe ki gbogbo iyanu eto isuna owo ti mo ti
padanu pada l'oruko Jesu.
4. Gbogbo ifowosowopo okunkun ti se atilehin fun ogun alalobo ninu aiye mi, e tuka pelu ina.
5. Mo ko gbogbo emi ile gbigbe sile, Mo gba ojurere ati orirere latoke wa.
JESUS IS LORD.
No comments