news

Followers

PRAYER POINTS FOR TODAY 5TH FEBRUARY, 2021 BY PASTOR TIMOTHY OGUNYEMI

 PRAY WITH (ISAIAH 53)




1) Lord, I thank You for You are the provider of goodthings.


2 ) Every door opened to spiritual robbers in my life, be shut by mercy in Jesus' name.


3 ) Any evil consequences of my father's house appearing as spiritual robber in my life, be swallowed by the Blood of Jesus.


4) Any power that has swallowed my inheritance, vomit it by fire in Jesus' name.


5) My children shall not walk into destruction.


6) Every evil wind assigned to be blowing my blessings 

away from me, be diverted in Jesus' name.


7) Every ancient gate shutting my portion away from me, crash into pieces in Jesus' name.


8 ) Good opportunities that have ever passed my life and ministry, reappear by mercy.


9 ) Spirit of boldness, possess me to recover my 

portion in Jesus' name.


10) Strongman of my ancestors, release my inheritance in your hand by fire.


YORUBA TRANSLATION:


 KOKO ADURA FUN 05/02/21 GBADURA PELU ISAYA 53


1 . Oluwa, modupe lowo Re ni tori Iwo ni Olupese oun ti o dara.


2 . Gbogbo ilekun ti o si fun ole emi ninu aiye mi, e ti nipa aanu ni l'oruko Jesu.


3. Gbogbo abajade ibi ile baba mi to nfarahan bi ole emi ninu.aiye mi, Eje Jesu gbe mi.


4. Gbogbo agbara to ti gbe ogun ini mi mi, e po pelu ina ni l'oruko Jesu.


5. Awon omo mi ki yio rin ni ona iparun.


6. Gbogbo afefe okunkun ti a yan lati ma fe awon ibukun mi sonu lodo mi, e pada ni l'oruko Jesu.


7. Gbogbo enu ibode okukun ti o nti ipin mi kuro lodo mi, e fo si wewe ni l'oruko Jesu.


8 . Anfaani dada ti o ti koja kuro ninu aiye mi ati ise iranse mi, e pada nipa aanu.


9 . Emi igboya, gbe mi wo lati gba ipin mi pada ni l'oruko Jesu.


10. Alagbara iranderan mi, fi ogun ini mi ti o wa ni owo re sile pelu ina.

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts