news

Followers

PRAYER POINTS FOR FRIDAY 22ND JANUARY 2021 BY PASTOR TIMOTHY OGUNYEMI

PRAY WITH (PSALM 18)


1. Worship Him with a song in spirit and in truth.

2. Oh Lord, give me grace to be outstanding.

3 . Father, make me ten times better than I am right now in Jesus' name.

4 . Power assigned to waste my efforts, be wasted in Jesus' name.

5 . Whosoever is denying me of my portion, my Father, terrify them in Jesus' name.

6. I repent of any way I have opened the door to evil in my life in Jesus' name.

7. I rescue my destiny from the hand of the oppressors in Jesus' name.

 

YORUBA TRANSLATION:


KOKO ADURA FUN 21/01/21 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 18 

1. Fiyin Fun pelu orin ninu emi ati ninu otito.

2. Oluwa, fun mi ni ore-ofe lati ta yo.

3. Baba, je ki n dara lemewa ju bi mo ti wa yi lo l'oruko Jesu.

4. Agbara ti ayan ti mi lati fi akitiyan mi sofo, e sofo danu l’oruko Jesu.

5 . Enikeni to nfi eto mi dun mi, Baba mi, seru ba won ni l'oruko Jesu.

6 . Mo ronupiwada kuro ninu gbogbo ibi ti mo ti gba si ilekun sile fun ibi ninu aiye mi l'oruko Jesu.

7. Mo gba ayanmo mi kuro l'owo awon aponiloju ni oruko Jesu.


By Pastor Timothy Ogunyemi

Email: [email protected]

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts