1. LORD, I celebrate You for making all things work
together for good in my family.
2. Shout, 'God of Mercy' 21 times, glory of my marriage, begin to manifest now in Jesus' name.
3. My Father, my Father, anoint my home and family
with the oil of favour.
4. Strange sickness, you are a stranger in my family, be
destroyed in Jesus' name.
5. Every negative traditional marriage rites and covenants, be destroyed by the Blood of Jesus.
6. Generational personal curse working against my
marriage and home, be swallowed by the Blood of
Jesus.
7. Heavenly blessing, rain upon my marriage now.
8. Curse of barreness, break by the Blood of Jesus.
9. Judgment of hardship, be revoked be the name of
Jesus.
10. Covenant of multiple marriage, be revoked in Jesus'
name.
Yoruba translation!
KOKOO ADURA FUN 19/10/20
GBADURA PELU ORIN DAFIDI 89
1. OLUWA, modupe tori wipe o gba oun gbogbo laye
lati sise fun rere ninu ebi mi.
2. Pariwo Olorun Aanu ni igba mokanlelogun, ogo
igbeyawo mi, bere sin i fara han lesekese ni oruko Jesu.
3. Baba mi, Baba mi, fi ororo ojurere yan ile mi ati ebi mi
ni oruko Jesu.
4. Aisan ajeji, alejo l'oje ninu ebi mi, parun mi oruko
Jesu.
5. Gbogbo eto asa idana ibile okunkun ati majemu, Eje Jesu fo da nu.
6. Egun iranderan eleyi ti o nsise lodi si igbeyawo ati ile mi, Eje Jesu gbe mi.
7. Ibukun orun, ro si ori igbeyawo mi lesekese.
8. Egun iyagan, fo nipase Eje Jesu.
9. Idajo inira, yi pada nipase Eje Jesu.
10. Majemu igbeyawo pupo, Eje Jesu yi o danu l'oruko
Jesu.
No comments