BY OGUNYEMI OLUSEGUN T
PRAY WITH PSALM 18
1. Worship Him with a song in spirit and in truth.
2. Oh Lord, give me grace to be outstanding.
3 . Father, make me ten times better than I am right now in Jesus' name.
4 . Power assigned to waste my efforts, be wasted in Jesus' name.
YORUBA EDITION
1. Fiyin Fun pelu orin ninu emi ati ninu otito.
2. Oluwa, fun mi ni ore-ofe lati ta yo.
3. Baba, je ki n dara lemewa ju bi mo ti wa yi lo l'oruko Jesu.
4. Agbara ti ayan ti mi lati fi akitiyan mi sofo, e sofo danu l’oruko Jesu.
Jesus is Lord no controversy.
No comments