BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN T
PRAY WITH PSALM 121
1. My Father,, equip me with what will make me acceptable before helpers in Jesus’ name.
2. Anything in my future waiting to disgrace me be reserved in Jesus’ name.
3. Enemies of my help, you shall not triumph over me in Jesus’ name.
4.Every spiritual vails covering my face from recognizing my helpers, catch fire.
5. God of mercy give me help from all my troubles. For vain is the help from
man.
YORUBA EDITION
1. Baba mi, kun mi pelu awon nkan ti mo nilo lati je itewogba niwaju awon oluranlowo mi, l’oruko Jesu.
2. Ohunkohun ti o wa ninu ojo ola mi ti nduro lati doju ti mi, yipada l’oruko Jesu.
3. Awon ota iranlowo mi, e o ni bori mi ni oruko Jesu.
4. Gbogbo iboju okunkun, ti o bo oju mi lati maa da awon oluranlowo mi mo, gbina.
5. Olorun aanu, fun mi ni iranlowo kuro ninu gbogbo idamu mi, nitori wipe asan ni iranlowo eniyan. Amin
Jesus is Lord no controversy.
No comments