BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN T.
1. Father I thank you for your grace in my life.
2. Every padlock of the power of darkness that has tied me down to the same
spot, break by fire in Jesus’ name.
3. Every strange magnet magnetizing me to wrong help and helpers, be
neutralized by the Blood of Jesus.
4. I command the earth and all the elements to cooperate with me in Jesus’ name.
5. Let every satanic gate that has locked me out of my inheritance open now in
Jesus’ name.
6. Power to prevail in battle of destiny possess me in Jesus’ name.
YORUBA EDITION
1 Baba ese fun ore ofe yin lori aye mi.
2. Gbogbo agadagodo agbara okunkun ti o ti so mi mole si oju kan, fo pelu ina
ni oruko Jesu.
3. Gbogbo onfa ajoji eleyi ti on fa mi lo si ibi iranlowo odi ati oluranlowo odi, e
di asan pelu eje Jesu.
4 Mo pase fun aye ati oun gbogbo ti o wa ninu re, ki o fi owo so owo po pelu
mi ni oruko Jesu.
5. Je ki gbogbo enu bode okunkun ti o ti ti mi jade kuro ninu ipin mi si lesekese bi ni oruko Jesu.
6 Agbara lati bori ninu ogun ayanmo gbe mi wo ni oruko Jesu.
Jesus is Lord no controversy.
No comments