BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN T
1. Father, I thank You for Your power to rescue me in Jesus’ name.
2. Shout Holy Spirit reveal me to my helpers in Jesus’ name.
3. Every spirit of error, that hinders prophecies, catch fire in Jesus’ Name.
4. Anointing of wisdom that attract helpers, possess me in Jesus’ name.
5.Holy Spirit equip me with what will make me acceptable before my helpers.
YORUBA EDITION
1. Baba, modupe fun agbara Re lati gba mi, ni oruko Jesu.
2. Pariwo, Emi Mimo fi mi han oluranlowo mi ni oruko Jesu.
3.Gbogbo emi asise ti da asotele duro ninu aiye mi, gbina sonu ni oruko
Jesu.
4. Ifami ororo yan ogbon, eleyi ti o nfa oluranlowo, gbemi wo ni oruko Jesu.
5. Emi Mimo, gbe oun ti yo je kin je itewogba niwaju oluranlowo wo mi.
I prophesy to your life, The glory of God will shine on your way.
Jesus is Lord no controversy.
No comments