BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN T
1. Lord, I thank You for You are merciful
2. Lord, instruct my children and teach them in the way they should go.
3. I withdraw my name from the register of frustrated people in Jesus’ name.
4. God of mercy, give me help in unusual places in Jesus’ name. Amen.
YORUBA EDITION
1.OLORUN, modupe l’owo Re tori wipe O je alaanu.
2. Olorun, to awon omo mi ki O si ko won ni ona ti o ye ki won lo.
3. Mo yo oruko mi kuro ninu iwe akosile awon ti o ti jakule ni oruko Jesu.
4. Olorun aanu, fun mi ni iranlowo ni ibi ti ko wo po ni oruko Jesu. Amim.
Jesus is Lord no controversy.
No comments