BY OGUNYEMI OLUSEGUN T
1. Father, I thank You for Your servant that brings liberation to those whose lives are in bondage.
2. You spirit of pride and error, I bind You in Jesus’ name.
3. Voice of darkness in my foundation be silent in Jesus’ name.
4. Where is my prophet, appear to me by mercy.
5. Say, fire of the Holy Spirit surround me and my children. In Jesus name Amen.
YORUBA EDITIONI
1. Baba modupe fun iranse Re ti O mu itusile wa fun gbogbo awon aye ti o wa ninu ibode.
2. Iwo emi igberaga ati asise, mo de o ni oruko Jesu.
3. Ohun okunkun ninu ipile mi, dake ni oruko Jesu.
4. Nibo ni woli mi wa, farahan nipase aanu ni oruko Jesu.
5. So wipe ina Emi Mimo, yi emi ati awon omo mi ka. Loruko Jesu. Amin
Jesus is Lord no controversy .
No comments