news

Followers

COMMAND YOUR DAY PRAYER POINTS FOR TODAY TUESDAY 14TH SEPTEMBER 2021

BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN T









1. Jesus, I thank You for Your sacrifice.


2. Lord, forgive my wrong decisions to go down to Egypt and redeem me of 

its implication.


3. Father, it is written in Your Word that, ‘strangers shall be my nursing mother’. Therefore, from today let total stranger help me.


4.Oh Lord my God, cause me to access help from men of nations of different 

color and languages in Jesus’ name.

 

5.Father, it is written that, ‘the wealth of the gentiles shall come to me’. 

Therefore, let the help of gentiles locate me.


          YORUBA EDITION


1. Jesu, modupe lowo Re fun irubo Re.


2. Oluwa, dariji mi fun ipinu ti o to lati pada lo si ijibiti ki o si gbami lowo abajade re.

 

3. Baba, a ti ko ninu oro Re pe awon ajeji ni yio fun mi ni omu. Fun idi eyi, lati oni lo, jeki awon ajeji patapata ran mi lowo.


4. Oluwa, Olorun mi o, ran mi lowo lati ri iranlowo gba lati owo awon eniyan 

Orile-ede ti oniruru awo ati ede ni oruko Jesu.


5.Baba, gege bi a ti ko wipe oro awon kenferi yio wa sodo mi, fun idi eyi jeki 

iranlowo awon kenferi wa mi ri.


   Jesus is Lord no controversy.

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts