BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
PRAY WITH PSALM 29
1. Lord, I thank You because You are a merciful God that forgives sins. Sing a song of praise to the LORD'S.
2. Lord, forgive me for all my wrong doings and disobedience to Your voice, have mercy on me in the name of Jesus.
3. Grace to hear Your voice and to comply, fall on me now.
4. You arrow of unbelief and doubt to the voice of the Lord, come out of my life in the name of Jesus.
5. The spirit of faith to believe in the voice of God, fall on me. Amen.
YORUBA EDITION
1. Oluwa, mo fi ope fun O nitori Olorun alaanu ti n dariji ni O. Ko orin iyin si Olorun.
2. Oluwa, dariji mi fun gbogbo iselodi ati aigboran ti mo ti se si ohun Re, saanu mi Oluwa.
3. Ore-ofe lati gba ohun Re gbo ati lati tele ohun Re, da lu mi l'oruko Jesu.
4. Iwo ofa aigbagbo ati iyemeji si ohun Olorun, jade laiye mi l'oruko Jesu.
5. Emi igbagbo lati gba ohun Olorun gbo, wo inu mi l'oruko, Amim.
Jesus is Lord no controversy
No comments