By Pastor Ogunyemi Olusegun Timothy
Email: [email protected]
PRAY WITH PSALM 45
Praise God this morning.
1. Lord, let this moment be my restoration moment in
Jesus' name
2. My missing bone, locate me by mercy in Jesus' name.
3. God of Mercy, let my children stand out in life in Jesus' name.
4. By mercy, I escape every trap of permanent death in
Jesus' name.
5. Nobody will pay me condolence visit this year in Jesus' name.
YORUBA EDITION
YIN OLORUN LONI.
1. Oluwa, je ki akoko yi je akoko imupada bosipo mi ni oruko Jesu.
2. Egungun iha mi to sonu, sawari mi nipa aanu ni oruko Jesu
3. Olorun Aanu, je ki awon omo mi ta yo l'aiye ni oruko Jesu.
4. Nipa aanu, mo yo ninu ikekun iku ni oruko Jesu.
5. A ko ni bo bata ofo si enu ona mi ninu odun yi ni oruko Jesu.
JESUS IS LORD.
No comments