news

Followers

COMMAND YOUR DAY: PRAYER POINTS FOR MONDAY 5TH APRIL 2021

BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY

Email: [email protected]


PRAY WITH PSALMS 44



1. I praise You Lord for Your mercy that endures forever.

2. Every human tradition that has tied down my destiny

be broken and release me in Jesus' name.

3. Every snare of human tradition, be dismantled in

Jesus' name.

4. Holy Spirit, make me wiser than my enemies.

5. Rod of the wicked attacking my testimony, be wasted in Jesus' name.

6. I remove and reject all inherited spirit of setback in Jesus' name.

7. I receive everything that I have lost to foundational

human tradition in Jesus' name.

8. I possess my possession stolen by the evil altar in Jesus' name.

9. My Father, my Father, be a shield for me in every situation in Jesus' name.

10. Demonic mirror projected to monitor me, crash by thunder.



YORUBA EDITION


GBADURA PELU ORIN DAFIDI 44

1. MO YIN O Oluwa fun aanu Re ti o wa titi lailai.

2. Gbogbo asa ti eniyan ti o so ayanmo mi mole, fo ki o si yonda mi l'oruko Jesu.

3. Gbogbo idekun awon asa ti eniyan, tuka ni oruko Jesu.

4. Emi Mimo, mu mi gbon ju won ota mi lo.

5. Opa awon eniyan buburu ti ntako eri mi, sofo danu l'oruko Jesu.

6. Mo yo jade mosi ko emi ifasehin ti ajogunba ni oruko Jesu.

7. Mo gba ohun gbogbo ti mo ti padanu sinu asa ti eniyan lati inu ipile mi l'oruko Jesu.

8. Mo gba ini mi eyi ti a ti fi pepe okunkun ji lo pada l'oruko Jesu.

9. Baba mi, Baba mi, je ibi isadi mi ninu oun gbogbo l'oruko Jesu.

10. Jigi okunkun ti a ran lati ma to pin pin mi, tuka pelu ara.


BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY

Email: [email protected]

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts