By Pastor Ogunyemi Olusegun Timothy
Email: [email protected]
PRAY WITH PSALM 1
1. Anointing of success and fruitfulness, possess me in
Jesus' name.
2. Every good things that Jesus' death made available for me, I claim in Jesus' name'
3. I receive grace to do the will of God and serve Him in Jesus' name.
4. I will not die with my God's given potentials in Jesus' name.
5. I receive grace to create impact in my generation in Jesus' name.
YORUBA EDITION
1. Ifami ororo yan si ise rere ati ileso, gbe mi wo l'oruko
Jesu.
2. Ohun rere gbogbo ti iku Jesu ti pese sile fun mi, mo gba l'oruko Jesu.
3. Mo gba ore-ofe lati se ife Olorun ati lati sin li oruko Jesu.
4. Emi ki yi o ku pelu gbogbo anfaani Olorun inu aiye mi l'oruko Jesu.
5. Mo gba ore-ofe lati sise to lapere ninu iran mi l'oruko.
No comments