news

Followers

PRAYER POINTS FOR TODAY WEDNESDAY 24TH MARCH 2021 BY PASTOR OGUNYEMI T.O.

PRAY WITH PSALMS 15; 105


1. I thank the Lord because He is the bondage breaker and the Great Physician.


2. Holy Ghost Fire, purge every defilement away from my life in Jesus' name.

3. Every authority assigned to torment me, expire in Jesus' name.

4. Anything planted in my body to oppress me, come out now by fire in Jesus' name.

5. Blood of Jesus, sanitize my spirit, soul and body in Jesus' name.

6. Shout Blood of Jesus 21 times, separate me from the sins of my ancestors.

7. O Lord, teach me to die to self.

8. O Lord, establish me as a holy person unto You in Jesus' name.

9. Every spirit rooted in fornication, come out of my life with all your roots in Jesus' name.

10. I loose myself from every evil influence.


YORUBA VERSION:

KOKO ADURA FUN 24/03/21 

GBADURA PELU ORIN DAFIDI 15 & 105

1. MODUPE, l'owo Oluwa nitori oun ni Olufo igbekun

ati onisegun nla.

2. Ina Emi Mimo, we gbogbo idibaje kuro ninu aiye mi

l'oruko Jesu.


3. Gbogbo ase ti a yan lati ni mi l'ara, wa s'opin l'oruko Jesu.

4. Ounkoun ti a gbin sinu ago ara mi lati pon mi l'oju jade bayi pelu ina l'oruko Jesu.

5. Eje Jesu, we emi mi, okan mi ati ara mi mo l'oruko Jesu.

6. Pariwo Eje Jesu nigba mokanlelogun, ya mi soto kuro ninu ese awon baba nla mi.

7. Oluwa, ko mi lati di oku si ese.

8. Oluwa, fi ese mi mule gege bi eniyan mimo si O l'oruko Jesu.

9. Gbogbo emi ti o fi gbongbo mule sinu agbere, jade kuro ninu aiye mi ti gbongbo ti gbongbo l'oruko Jesu.

10. Mo tu ara mi sile kuro l'owo afarawe ibi.


No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts