news

Followers

PRAYER POINTS FOR TODAY TUESDAY 23RD MARCH 2021 BY PASTOR OGUNYEMI T.O.

PRAY WITH PSALMS 5


1. I thank the Lord for You are the only that answers prayer.

2. Every poison and contamination in my blood, be flushed out.

3. You spirit of lust, jump out of my life in Jesus' name.

4. Whatever I have lost in my yesterday that is affecting my performance today, Lord by mercy restore it.


5. You wind of spiritual death, go back to your sender.

6. You arrow of lust, you are in a wrong place, backfire.

7. Ancestral bondage of lust affecting my life negatively, break by fire.

8. Destroyer of inheritance, loose your grip upon my life.

9. Every power that does not want me to go and fulfill my destiny, evaporate by fire.

10. Every impossible situation in my life be converted to divine possibility in Jesus' name


YORUBA VERSION:

KOKO ADURA FUN 23/03/21

 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 5

1. MODUPE, l'owo Oluwa nitori oun nikan lo ngbo adura.

2. Gbogbo majele ati ibaje ninu eje mi, fo jade.

3. Iwo emi ifekufe, fo jade ninu aiye mi l'oruko Jesu.

4. Ounkuoun ti mo ti padanu sinu ana mi, eyi ti o npa oni mi lara, Oluwa, pelu aanu da pada.

5. Iwo iji iku tie mi, pada lo sodo eni ti o ran o.

6. Iwo ofa ifekufe, ibi ti ko to ni o, pada.

7. Igbekun abalaye ti ifekufe ti o faramo aiye mi lode, japelu ina.

8. Arungun ini, so agbara re nu l'ori aiye mi.

9. Gbogbo agbara ti ko fe ki nkoja lati mu ayanmo mi se, poora pelu ina.

10. Gbogbo oun ti ko sese ninu aiye mi, yipada di osese ni oruko Jesu

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts