news

Followers

PRAYER POINTS FOR TODAY THURSDAY 25TH MARCH 2021 BY PASTOR OGUNYEMI T.O.

 PRAY WITH PSALMS 22



1. I thank You for giving me the strength to tread upon my worst enemy.


2. Lord, help me to enjoy the fruit of my labour.


3. Continuous blessings of the Lord, rest on my work in Jesus' name.


4. My labour over my children will not end in futility in Jesus' name.


5. Days of God's open treasure will be evident in my life.


6. Lord, expose agent of darkness around my inheritance.


7. Lord, open my eyes to recognize gifted people around me in Jesus' name.

 

8. Lord, give me insight to know the hour of my visitation in Jesus' name.


9. I take back every property of mine stolen by evil agents.


YORUBA VERSION:

KOKO ADURA FUN 24/03/2021 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 22


1. MODUPE l'owo Re nitori O fun mi ni okun lati rin koja l'ori ota mi.


2. Oluwa, ran mi l'owo lati gbadun eso lala mi.


3. Ibikun Oluwa ti ko l'opin, ba s'ori ise mi l'oruko Jesu.


4. Lala mi l'ori awon omo mi ki yio ja si asan l'oruko Jesu.


5. Awon ojo isura Olorun ti o si sile ma f'arahan ninu aiye mi.


6. Oluwa, tu asiri asoju okunkun ni ayika ini mi.


7. Oluwa, si oju mi lati da awon ti o ni ebun ni ayika mi mo.


8. Oluwa, fun mi ni oye lati mo wakati ibewo mi l'oruko Jesu.


9. Mo gba gbogbo dukia mi ti asoju okunkun ji pada.


By:

Pastor Ogunyemi T.O.

Email: [email protected]


No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts