PRAY WITH PSALMS 1
2. My Father, my Father, forgive me for disobeying your guidelines.
3. Every of my lost inheritance to the dungeon of disobedience, be restored by mercy.
4. Spirit of obedience that will prevent me from losing
my inheritance, Lord release it on me.
5. Holy Ghost, show me the secret of what I am passing
through in Jesus' name.
6. Wasting power of my yesterday, be wasted in Jesus' name.
7. I receive grace to restitute my past in Jesus' name.
8. Help me oh Lord to discover my real self.
9. Every habitation of financial losses in my life, become desolate in Jesus' name.
10. Lord, forgive me of every unfaithfulness in paying my
covenant dues in Jesus' name
YORUBA VERSION:
KOKO ADURA FUN 21/03/21 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 1
1. OLUWA, modupe l'owo Re fun ororo adura titun eyi ti a dale mi l'ori fun ise mi ti o kan.
2. Baba mi, Baba mi, dari gbogbo aigbonran si liana Re ji mi.
3. Gbogbo ini mi ti o bo sinu ogbun isale ti aigbonran, pada pelu aanu.
4. Emi igbonran ti yio ko mi yo lati ma padanu ini mi, Oluwa, yonda e fun mi.
5. Emi Mimo, tu asiri oun ti mo nla koja le mi l'owol'oruko Jesu.
6. Agbara afini sofo ti o wa ninu ana mi, sofo danu l'oruko Jesu.
7. Mo gba ore-ofe lati se atunse igba atijo mi l'oruko Jesu.
8. Raan mi l'owo Oluwa lati se awari ara mi gangan.
9. Gbogbo ibugbe sisofo eto isuna ninu aiye mi, di ahoro
l'oruko Jesu.
10. Oluwa, dariji mi fun gbogbo aisoto ninu sisan eje awon eje ti mo da majemu l'oruko Jesu.
By Pastor Timothy Ogunyemi
Email: [email protected]
No comments