PRAY WITH PSALM 18
1. Sing new song in spirit and in understanding.
2. O Lord, send Your angel to help me in the time of spiritual warfare.
3. Hosts of Heaven, surround my altar of
prayer.
4. The secret of what am passing through, Holy Spirit
reveal it to me.
5. Every lost virtue, return back by mercy.
6. Fire of revival from Heaven above, possess me in Jesus' name.
YORUBA EDITION
1. Ko orin titun ninu emi ati ninu oye.
2. Oluwa, ran angeli Re lati ran mi lowo nigba ija ogun emi.
3. Ogun orun, yi pepe adura mi ka.
4. Asiri oun ti mo nla koja, Emi-Mimo, tu fun mi.
5. Gbogbo amuye ti mo ti sonu, pada pelu aanu.
6. Ina isoji lati orun wa, gbe mi wo ni oruko Jesu.
No comments