news

Followers

PRAYER POINTS FOR TODAY FRIDAY 26TH MARCH 2021 BY PASTOR OGUNYEMI T. O.

 PRAY WITH PSALMS 31



1. I thank the Lord for His great deliverance from the

power of the evil one. 


2. I receive deliverance from the spirit of slumber that attacks in the midst of battle.


3. Weapon of oppressor, backfire in Jesus' name.


4. I come against every attempt of the devil to oppose and destroy the Gospel in our city in Jesus' name.


5. I receive ability to discern the spirit in operation in every situation.


6. Every gang up against my inheritance, be completely scattered in Jesus' name.


7. O God, arise, let my tears expire.


8. Every power assigned to put off my light, receive confusion in Jesus' name.


9. Powers that wants to terminate me because of my inheritance, be terminated by fire.


10. Lord, convert my loss to gain in Jesus' name.


YORUBA VERSION:


KOKO ADURA FUN 26/03/2021

GBADURA PELU ORIN DAFIDI 31


1. MODUPE l'owo Oluwa fun itusile Re nla kuro l'owo agbara ika eniyan.


2. Mo gba itusile kuro l'owo emi ongbe ti ma nkolu ni ni oju ogun.


3. Irinse aninilara, pada l'oruko.


4. Mo se lodi si gbogbo igbese esu lati tako ati lati pa ihinrere run ni ilu wa l'oruko Jesu.


5. Mo gba agbara lati ni imolra emit i o nsise ninu gbogbo isele.


6. Gbogbo ikorajopo lodi si ini mi, tuka patapata l'oruko Jesu.


7. Olorun, dide jeki omije mi dopin.


8. Gbogbo agbara ti a yan lati pa imole mi, gba iporuru l'oruko Jesu.


9. Awon agbara ti won fe pa mi nitori ini mi, e parun pelu ina.


10. Oluwa, so ofo mi di ere l'oruko Jesu.


BY PASTOR OGUNYEMI T. O.

EMAIL: [email protected]


No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts