news

Followers

PRAYER POINTS FOR TODAY 15TH MARCH, 2021 BY PASTOR TIMOTHY OGUNYEMI

  PRAY WITH PSALMS 31



1. I thank the Lord for His great deliverance from the power of the evil one. 


2. I receive deliverance from the spirit of slumber that attacks in the midst of battle.


3. Lord, contend with them that contend with me.


4.. By fire, by force, Lord, launch me into my next level in Jesus' name.


5. God of Mercy rain preserve my inheritance for me for coming generation legacy.


6. Every hole in the container of my life, be blocked in Jesus' name.


7. I refuse to be deaf, dumb and blind spiritually.


8. Lord, help me never to miss my day of visitation.


9. Lord, show me what to do in oeder to defend my inheritance.


10. Oh Lord, defend my portion in Jesus' name. 


YORUBA TRANSLATION:


KOKO ADURA FUN 17/10/20 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 31


1. MODUPE l'owo Oluwa fun itusile Re nla kuro l'owo agbara ika eniyan.


2. Mo gba itusile kuro l'owo emi ongbe ti ma nkolu ni ni oju ogun.


3. Oluwa, gbogun ti awon ti o ngbogun ti mi.



4. . Pelu ina ati ipa, Oluwa, ti mi sinu ipele mi ti o kan l'oruko Jesu.


5. Olorun Ojo Aanu, pa ini mi mo fun mi fun apere rere fun iran ti o nbo.


6. Gbogbo ibi ti aiye mi ti njo, di l'oruko Jesu.


7. Mo ko lati diti, ya odi ati f'oju nipa tie mi.


9. Oluwa, ran mi l'owo lati ma padanu ojo ibewo mi.


9. Oluwa, fi ohun ti mo ma se lati daabo bo ini mi han mi.


10. Oluwa, daabo bo ipin mi l'oruko Jesu.


By Pastor Timothy Ogunyemi

Email: [email protected]

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts