news

Followers

COMMAND YOUR DAY: PRAYER POINTS FOR TUESDAY 30TH MARCH 2021

 BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY


PRAY WITH PSALM 5



1. Anointing of success and fruitfulness, possess me in

Jesus' name.

2. Every power assigned to cut shot my assignment, be

wasted in Jesus' name.

3. Every good things that Jesus' death made available for me, I claim in Jesus' name'

4. I receive grace to do the will of God and serve Him in Jesus' name.

5. I cancel all appointment with sorrow, tragedy and

losses in Jesus' name.


  YORUBA EDITION

1. Ifami ororo yan si ise rere ati ileso, gbe mi wo l'oruko

Jesu.

2. Gbogbo agbara ti a yan lati ge ise ayanmo mi kuru, e sofodanu l'oruko Jesu.

3. Ohun rere gbogbo ti iku Jesu ti pese sile fun mi, mo gba l'oruko Jesu.

4. Mo gba ore-ofe lati se ife Olorun ati lati sin li oruko Jesu.

5. Mo fa gi le gbogbo ipade pelu ibanuje, ofo ati adanu ni oruko Jesu.


BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY

EMAIL: [email protected]

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts