news

Followers

PRAYER POINTS FOR 19TH, JANUARY 2021 BY PASTOR TIMOTHY OGUNYEMI

 *PRAY WITH PSALM 51* 


1). Sing a new song to your Restorer of joy.

2). Foundation of discomfort in my life, dry up now in Jesus' name.

3). Every stubborn pursuer of my life, turn back and perish by fire. 

4). Strength from above, boost my energy to run the race set before me in Jesus' name.

5). My Father, my Father, feed me with the food of

champions in Jesus' name.


6). Lord, inject into me spiritual vitamins that boost my appetite to feed in your Word and sustain me in evil days in Jesus' name.

7). I bind and paralyze

every strongman of fear in my life in Jesus' name.

8). I loose myself from the bondage of fear in Jesus' name.

9). Every problem introduced by fear into my life, depart

now in Jesus' name.

10). Arrow of distress, jump out of my life in Jesus' name


 *KOKO ADURA FUN 19/01/21 GBADURA PELU ORIN DAFIDI 51* 

1. Ko orin titun si Oludapada ayo re.

2. Ipinle inira ninu aiye mi, gbe nisinsiyi ni oruko Jesu.

3. Gbogbo ogun aleni ma deyin okunkun inu aiye mi, epeyinda ki e si parun pelu ina.

4 . Agbara lati oke wa, kun okun mi lati sa ere ije mi ti o wa ni waju mi l’oruko Jesu.

5 . Baba mi, Baba mi, fun mi ni ounje awon asegun je l’oruko Jesu.

6. Oluwa, fun mi ni ounje amusaralore ti emi ti yio mu mi pongbe fun jije oro Re ti yio gbemi ro ni ojo ibi l’oruko Jesu.

7. Mo gbede mo si yalaro gbogbo okunrin alagbara eru inu aiye mi l’oruko Jesu.

8. Mo tu ara mi sile kuro ninu igbekun eru l’oruko Jesu.

9. Gbogbo idamu ti iberu mu wo aiye mi, e kuro ninu aiye

mi nisinsiyi l'oruko Jesu.

10. Ofa inira, fo jade ninu aiye mi l'oruko Jesu.


Email: [email protected]

No comments

Poster Speaks

Poster Speaks/box

Trending

randomposts