Read: PSALM 3: 1-8
1. Sing a new song to the Lord and the rock of our salvation.
2. Oil of wisdom and organization with the fear of God fall in all the leaders of this country in the name of
Jesus.
3 Every mark of hatred that stops people from helping
me, come out by fire in the name of Jesus.
4. Garment of glory that was lost from my father, restore
it by mercy in the name of Jesus.
5. Every privilege that I had lost in the past return to me
by fire in the name of Jesus.
6. You covenant that turns the day of joy to the day of
sorrow, Blood of Jesus consume it.
7. Every monitoring spirit over my case, catch fire in the name of Jesus
KOKO ADURA FUN 09/12/20 ORIN DAFIDI 3:1-8
1. Ko orin tuntun si Oluwa ati apata igbala wa.
2. Ororo ogbon ati isakoso pelu iberu Oluwa, ma bo l'ori awon adari wa l'oruko Jesu.
3. Ami ti won kii se l'ore l'ara mi, ba ina jade.
4. Aso ogo to bo sonu l'ara baba mi, faanu da pada simi l'ara
l'oruko Jesu.
5. Anfaani ti mo ti padanu latehinwa, pada wa pelu ina, l'oruko Jesu.
6. Iwo majemu to n so ojo ayeye di ojo esin, Eje Jesu gbemi l'oruko Jesu.
7. Gbogbo oju atopinpin l'ori oro mi, gbina daanu l'oruko Jesu.
No comments