BY PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
BIBLE READING: PSALM 8
1. Father, I thank You for making me a star in Jesus' name.
2. My destiny, hear the Word of God, manifest by fire in
Jesus' name.
3 . Every power keeping me away from my divine helpers, be destroyed in Jesus' name.
4. O God, arise and give me a turnaround miracle in Jesus' name.
5. God of mercy, arise and let my shame expire
in Jesus' name.
6. Every satanic panel set up against me, scatter in Jesus' name.
YORUBA TRANSLATION:
KOKO ADURA FUN MONDAY 28/12/20
PASTOR OGUNYEMI OLUSEGUN
BIBELI KIKA: ORIN DAFIDI 8
1. Baba, modupe lowo Re pe O se mi ni irawo to ntan ni oruko Jesu.
2. Ayanmo mi, gbo Oro Olorun, farahan pelu ina ni oruko Jesu.
3. Gbogbo agbara to nfami sehin lodo awon oloore mi, e s'ofo danu l'oruko Jesu.
4 . Olorun o, dide ki O fun mi ni iyanu to ma yi aiye mi pada ni oruko Jesu.
5 . Olorun aanu, dide ki O je ki itiju mi dopin ni oruko Jesu.
6. Gbogbo igbimo okunkun ti a gbe dide lodi si mi, e fo ka ni oruko Jesu.
Email: [email protected]
No comments