1 Father, I thank You for making me a star in Jesus' name.
2 My destiny, hear the Word of God, manifest by fire in
Jesus' name.
3 Every power keeping me away from my divine helpers, be destroyed in Jesus' name.
4 O God, arise and give me a turnaround miracle in Jesus' name.
5 God of mercy, arise and let my shame expire
in Jesus' name.
6 Every satanic panel set up against me, scatter in Jesus' name.
7 I rededicate my life to You my Lord use me for Your glory in Jesus' name.
8 As I am crossing over to the new month today, I am crossing with my good news. I buried every evil news in the name of Jesus.
KOKO ADURA FUN MONDAY 30/11/20 OGUNYEMI OLUSEGUN TIMOTHY
1. Baba, modupe lowo Re pe O se mi ni irawo to ntan ni oruko Jesu.
2. Ayanmo mi, gbo Oro Olorun, farahan pelu ina ni oruko Jesu.
3. Gbogbo agbara to nfami sehin lodo awon oloore mi, e s'ofo danu l'oruko Jesu.
4 Olorun o, dide ki O fun mi ni iyanu to ma yi aiye mi pada ni oruko Jesu.
5. Olorun aanu, dide ki O je ki itiju mi dopin ni oruko Jesu.
6. Gbogbo igbimo okunkun ti a gbe dide lodi si mi, e fo ka ni oruko Jesu.
7. Mo tun ara mi yonda si Iwo Oluwa mi, lo mi fun ogo Re ni oruko Jesu.
8 Bi mo ti n koja lo si inu osu titun loni, mo koja pelu iroyin rere mi. Gbogbo iroyin ibi mo si yin l'oruko Jesu.
No comments